Iṣẹ́ náà le bí ojú ẹja.
The work is as hard as a fish's eye.
Yorùbá · Adjectives · Level 1
Iṣẹ́ náà le bí ojú ẹja.
The work is as hard as a fish's eye.
Iṣẹ́ olùkọ́ ò lè gbè mí.
Teaching cannot support me financially.
Wọn kì í pa owó látinú iṣẹ́ yìí.
They don't make money from doing such work.
These are sentences where the word appears, matched automatically rather than hand-picked usage.