Má gbàgbé láti máa pa tẹlifíṣọ̀n.
Don't forget to turn off the television.
Yorùbá · Common Words · Level 1
Má gbàgbé láti máa pa tẹlifíṣọ̀n.
Don't forget to turn off the television.
Ọkùnrin yìí lọ́kàn láti dúró de ẹkùn
This man was courageous to have stood in the way of a tiger.
Ẹ má gbàgbé láti yán ọmọ nídìí ọ̀rọ̀
Don't forget to put subdots under the words.
These are sentences where the word appears, matched automatically rather than hand-picked usage.